Chidinma Òsùbà lyric

Òsùbà

Chidinma Chidinma
01 March 2022
74

Chidinma Òsùbà Lyrics

Ato gba rále oooo

Eberu kósi fun mi
Ayá o fo mi ooo
Aladé wura olorun tó ga ju
Olododo
Talo to ó
Taloju o lo? Oba mi
Eni to mówa
Oba to mo wa
To mohun gbogbo

Osuba olorun ijaya
Gbanigbani olorun a n saya
Eni to lemi mi, mo dé
Osuba olorun ijaya (osuba olorun ijaya)
Gbanigbani olorun a n saya
Eni to lemi mi mo dé

Olodumare ooo
Oba akoda ayé ooo
Ogbigba ti n gba alailara
Asoromayewun ooo
O gbeni ni ja
Keru o bo onija
O pin okun niya
O ji òku dide
Iba re maa re sir
Eleburuike ni ooo
Eni to mówa
Oba to mo wa
To mohun gbogbo

Osuba olorun ijaya (osuba olorun ijaya)
Gbanigbani olorun a n saya
Eni to lemi mi mo dé
Osuba olorun ijaya
Gbanigbani olorun a n saya
Eni to lemi mi mo dé

Onibu ore ooo
Jagun jagun ode orun oo
Oba ti nbe nibi gbogbo
Akijuba
Apejuba
Asajuba
Osuba re re
Osuba re re
Osuba re re ooo




Comments

You may also like these lyrics

00:00 00:00